Asamiisi
Ìrísí
Ara egbé ti ìlà-oòrùn àwon èdè Indo-Aryan (Indo-Aryan languages ni Assamese. Àwon tí ó ń so ó to mílíònù mérìnlá àbò (14.5 million). Orílè-èdè Asam ni wón ti ń so èdè yìí jù. Ìlà-oòrùn àríwá orílè-èdè India ni Asam wà. Àwon tí ó ń so èdè Assamese yìí tún wà ní Bhutan àti Bangladesh. Àkotó Bengah ni wón fi ń ko Assamese sílè. Ìbátan sì ni òun àti èdè Bengah: