Jump to content

Asamiisi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àtúnyẹ̀wò ní 13:13, 13 Oṣù Òwéwe 2017 l'átọwọ́ BlahmaBot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
(ìyàtọ̀) ← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju | Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí (ìyàtọ̀) | Àtúnyẹ̀wò tótuntunju → (ìyàtọ̀)

Assamese

Asamiisi

Ara ẹgbẹ́ ti ìlà-oòrùn àwọn èdè Indo-Aryan (Indo-Aryan languages ni Assamese. Àwọn tí ó ń sọ ọ́ to mílíọ̀nù mẹ́rìnlá àbọ̀ (14.5 million). Orílẹ̀-èdè Asam ni wọ́n ti ń sọ èdè yìí jù. Ìlà-oòrùn àríwá orílẹ̀-èdè India ni Asam wà. Àwọn tí ó ń sọ èdè Assamese yìí tún wà ní Bhutan àti Bangladesh. Àkọtọ́ Bengah ni wọ́n fi ń kọ Assamese sílẹ̀. Ìbátan sì ni òun àti èdè Bengah: