Jump to content

Asamiisi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àtúnyẹ̀wò ní 15:44, 12 Oṣù Ṣẹ̀rẹ́ 2007 l'átọwọ́ Loadewole (ọ̀rọ̀ | àfikún)
(ìyàtọ̀) ← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju | Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí (ìyàtọ̀) | Àtúnyẹ̀wò tótuntunju → (ìyàtọ̀)

Assamese

Asamiisi

Ara egbé ti ìlà-oòrùn àwon èdè Indo-Aryan (Indo-Aryan languages ni Assamese. Àwon tí ó ń so ó to mílíònù mérìnlá àbò (14.5 million). Orílè-èdè Asam ni wón ti ń so èdè yìí jù. Ìlà-oòrùn àríwá orílè-èdè India ni Asam wà. Àwon tí ó ń so èdè Assamese yìí tún wà ní Bhutan àti Bangladesh. Àkotó Bengah ni wón fi ń ko Assamese sílè. Ìbátan sì ni òun àti èdè Bengah: