Jump to content

Ọ̀fun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Esophagus
The digestive tract, with the esophagus marked in red
Details
PrecursorForegut
SystemPart of the digestive system
ArteryOesophageal arteries
VeinOesophageal veins
NerveSympathetic trunk, vagus
Identifiers
LatinOesophagus
TAA05.4.01.001
FMA7131
Anatomical terminology

Ọ̀fun ( /ˈsɒfəɡəs/), tí a tún mọ̀ sí ònfà óúnjẹ ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà ara inú tí ó dàbí okùn oníhò tí ó ń ṣíṣẹ́ gbígbé óúnjẹ láti ẹnu lọ sí inú ikùn tí ó wà ní ara gbogbo ohun abẹ̀mi tí ó bá ti ń jẹ tàbí mu ohun kóhun. fibromuscular. Ọ̀fun yí dà bí ahòho tí ó gùn ní ìwọ̀n mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n lára àgbàlagba ènìyàn tí ó rọra gba ẹ̀yìn okùn ohùn, ọkàn àti iṣan atẹ́gùn tàbí èémí kọjá, tí ó sì fẹnu sọlẹ̀ sí inú ikùn. Lásìkò tí a bá ń gbé óúnjẹ mì lọ́wọ́, gògóńgò yóò dípa lọ́wọ́ ẹ̀yín kí a má ba lè gbé óúnjẹ párí. [1]

Àwọn Ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Jacobo, Julia (24 November 2016). "Thanksgiving Tales From the Emergency Room". ABC News.