Boutros Boutros-Ghali
Ìrísí
Boutros Boutros-Ghali | |
---|---|
6th Secretary-General of the United Nations | |
In office 1 January 1992 – 31 December 1996 | |
Asíwájú | Javier Pérez de Cuéllar |
Arọ́pò | Kofi Annan |
Foreign Minister of Egypt | |
In office 1977–1991 | |
Secretary-General of Francophonie | |
In office 1997–2002 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kọkànlá 1922 Cairo, Egypt |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Egyptian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Leia Maria Boutros-Ghali |
Boutros Boutros-Ghali (Arabiki: بطرس بطرس غالي, Koptiki: Bουτρος Βουτρος-Γαλι) (ojoibi 14 November 1922) je ara ile Egypt to je diplomati to wa ni ipo gege bi Akowe Agba kefa Agbajo Iparapo awon Orile-ede (UN) lati January 1992 de December 1996. O je onimo eko ati Alakoso Oro Okere ile Egypti, Boutros Boutros-Ghali sakoso UN nigbati orisi idamu lagbaye, bi ituka Yugoslafia ati Ipaniyanrun Rwanda sele.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |