Jump to content

FIFA

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fédération Internationale de Football Association
MottoFor the Game. For the World
Ìdásílẹ̀May 21, 1904
TypeSports federation
IbùjókòóZürich, Switzerland
Ọmọẹgbẹ́208 national associations
Official languagesEnglish, French, German, Spanish, [1]
PresidentSepp Blatter
Websitewww.fifa.com

Egbe Ipapo Kariaye Ajose Boolu-Elese (Geesi:International Federation of Association Football; Faranse: Fédération Internationale de Football Association), to gbajumo gege bi FIFA, ni is the international agbarajo asejoba kariaye fun boolu-elese. Ibujoko re wa ni Zürich, Switzerland, be sini Aare re lowolowo bayi ni Sepp Blatter. FIFA ni o ni ojuse fun agbajo ati isejoba awon idije pataki boolu-elese, agaga Ife Eye Agbaye FIFA, to waye lati odun 1930.


  1. http://www.fifa.com/mm/document/affederation/federation/01/24/fifastatuten2009_e.pdf FIFA Statutes Aug 2009 see 8:1. Arabic, Russian and Portuguese are additional languages for the Congress. In case of dispute, English language documents are taken as authoritative.