Jump to content

Halojín

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Halogen)
Nonmetals in the periodic system
  Noble gases
  Halogens
  Other nonmetals
Apart from hydrogen metallloids are not placed in the p-block.

Àwọn halojín (tabi ẹ́límẹ́ntì halojín) ni egbe kan lori tabili idasiko awon elimenti to ni awon elimenti marun ti won fi kemika ba ara won tan, fluorínì (F), klorínì (Cl), brómìnì (Br), iodínì (I), àti astanínì (At). Elimenti 117 to je afowoda (ununseptium) na se e se ko je halojin. Ninu ifunloruko odeoni ti IUPAC, oruko egbe yi ni ẹgbẹ́ 17 (group 17) (tẹ́lẹ̀ bi: VII, VIIA, VIIB).

Egbe awon halojin nikan ni egbe ori tabili idasiko awon elimenti to ni awon elimenti ti won wa ni awon aye iwasi elo ti a mo meteeta ni igbonasi ati ifunpa onideede.