Ilé ìwòsàn
Ìrísí
Ilé Ìwòsàn ni ibùdó ìjọba tàbí ti aládàáni kan tí a yà sọ́tọ̀ tí àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ oníṣègùn òyìnbó ń ṣe àmúlò àwọn irinsẹ́ ìwòsàn láti fi ṣè ìtọ́jú àwọn aláàárẹ̀.[1] Ilé ìwòsàn tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ni ilé-ìwòsan gbogbo gbòò', idi ni wípé ó ní ó lè bójútó ìlera pàjáwìrì yálà aláàárẹ̀ tí wọ́n gbé dé ní pàjáwìrì láti ibi ìjàmbá ọkọ̀ tàbí ìjàmbá iná tàbí ajàkálẹ̀ àrùn tí ó dédé bẹ́ sílẹ̀ láìrò tẹ́lẹ̀. Ilé ìwòsàn tún ma ń ní ibùsùn àti iyàrá ìtọ́jú fún ẹni tí ìlera rẹ̀ yóò gba àìmọye ọjọ́ kí ó tó lálàáfíà.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Hospitals". World Health Organization (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 24 January 2018.